Jericho

839

Musik skapad av Peace Adewumi med Suno AI

Jericho
v3.5

@Peace Adewumi

Jericho
v3.5

@Peace Adewumi

Text
Introduction With Heavy trumpet And Brass
Wo lule, yo wo lule,
Awon odi Jericko, yo wo lule
Iwo sha ti ni gbagbo, iwo sha ti gbadura
Awon odi Jeriko, yo wo lule
Ihinrere ayo, ni momuwa fun o
Ohun o hun wa lo sokoto
Mbe lapo sokoto
Ki lo mpa o lekun, loni yo dekun ayo
Irohin alayo ni mo mu wa fun o 2x
Wo lule, yo wo lule,
Awon odi Jericko, yo wo lule
Iwo sha ti ni gbagbo, iwo sha ti gbadura
Awon odi Jeriko, yo wo lule
Interlude with Electric Organ and String
O wase titi titi, o rise se,
Gbogbo egbe ti san ju o lo
Oti gba gbogbo pali tan
Pabo sa lasan, loro re
O ti wa fe so reti nu
Sa ti mokan le, ireti mbe fun o
Interlude with Electri Guitar and Sax
O romo bi, tabo'nile yo o lenu
Gbese kami laya, ni ko je o ni simi
Aisan lorisirisi koje okan re bale rara
Yara ma bo, emi ti rona abayo
Bridge with melodious repetition
Call: Odi Jeriko
Resp: o woo lule owo o.
Call: Ninu aye mi,
Resp: o woo lule owo o.
Call: Ninu aye re.
Resp: o woo lule owo o.
Ogun ibanuje.
Resp: o woo lule owo o.
Call: Ai roko fe.
Resp: o woo lule owo o.
Call: Airomo gbe jo.
Resp: o woo lule owo o.
Call: Ogun amubo se
Resp: o woo lule owo o.
Call: Airije, rimu,
Resp: o woo lule owo o.
Call: Epe idile.
Resp: o woo lule owo o.
Call: Wa sodo Jesu mi
Resp: ko woo lule, ko wo o.
Call: kodi Jeriko o re.
Resp: o woo lule owo o.
Call: Wa gba jesu yi gbo.
Resp: o woo lule owo o.
Call: kaye re le layo.
Resp: o woo lule owo o.
Odi Jeriko.
Resp: o woo lule owo o.
Ogun faraoh
Resp: o woo lule owo o.
FADE OUT
Musikstil
Reggea, Brass, Bass, drums

Du kanske gillar

Cover av låten Buru Tala
v4

Skapad av RUMILA SOREN med Suno AI

Cover av låten Nanoka
v4

Skapad av Sándor Hodosi med Suno AI

Cover av låten شيلة يمنيه
v4

Skapad av ارسلان ارسلان med Suno AI

Relaterad spellista

Cover av låten Jon Dadam
v4

Skapad av Tanbur Dutorjonov med Suno AI

Cover av låten Mama Lib
v4

Skapad av Tamba Ngayenga med Suno AI